1. Ẹ káàrọ̀ [to an older person or more than one person]
2. Káàrọ [to a mate or colleague]
3. Ẹ káàsàn án
4. Ẹ kúròlé ẹ́
5. Ó dàárọ̀
6. Báwo ni?
7. Mọ wà dáadáa, ẹ ṣé
9. Ẹ ṣé , A dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run
10. Ẹbí ń kó?
11. Àwọn òbí rẹ ń kó?
13. Ó dàbọ̀
...a ó tẹ̀síwájú lọ́jọ́ iwájú
Today we shall start with greeting notions and some other notions in Yoruba language.
1. Good morning
2. Good morning
3. Good afternoon
4. Good evening
5. Good night 6. How are you?
7. I am fine, thank you 8. How is work?
9. Fine, thank God
10. How is family?
11. How are your parents?
12. Weldone
13. Good bye
... To be continued
2. Good morning
3. Good afternoon
4. Good evening
5. Good night 6. How are you?
7. I am fine, thank you 8. How is work?
9. Fine, thank God
10. How is family?
11. How are your parents?
12. Weldone
13. Good bye
... To be continued
Thanks for bringing back the culture... Most Yoruba tend to form forgetting their root... Am from Akwa-ibom but love your culture... Well-done MA...
ReplyDeleteE ku ise takun takun ti e n se Olootu Oyebimpe Olofin. Adura mi ni wipe Olorun a maa fun n yin se ooo. Amin.
ReplyDelete