Tuesday 11 April 2017

ASA IKINI NI ILE YORUBA

Ẹ káàrọ̀ ẹ̀yin ènìyàn wa,
Lónìí, a ó tẹsíwájú nínú Àṣà Ìkíni ní èdè Yorùbá 
A ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú Ìkíni ojoojúmọ́











1. Ẹ káàrọ̀ [to an older person or more than one person] 
2. Káàrọ [to a mate or colleague] 

3. Ẹ káàsàn án 
4. Ẹ kúròlé ẹ́
5. Ó dàárọ̀
6. Báwo ni? 
7. Mọ wà dáadáa, ẹ ṣé 
8. Báwo ni iṣẹ́? 

9. Ẹ ṣé , A dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run                                                      
10. Ẹbí ń kó? 
11. Àwọn òbí rẹ ń kó? 
12. Ẹ kú iṣẹ́
13. Ó dàbọ̀ 
...a ó tẹ̀síwájú lọ́jọ́ iwájú




Today we shall start with greeting notions and some other notions in Yoruba language.

1. Good morning
2. Good morning
3. Good afternoon
4. Good evening
5. Good night 6. How are you?
7. I am fine, thank you 8. How is work?
9. Fine, thank God
10. How is family?
11. How are your parents?
12. Weldone
13. Good bye
... To be continued

2 comments:

  1. Thanks for bringing back the culture... Most Yoruba tend to form forgetting their root... Am from Akwa-ibom but love your culture... Well-done MA...

    ReplyDelete
  2. E ku ise takun takun ti e n se Olootu Oyebimpe Olofin. Adura mi ni wipe Olorun a maa fun n yin se ooo. Amin.

    ReplyDelete